No. 102 · Orin Ẹri ati Ipe · Orin Iyin ati ỌpẹOlorun OlodumareLyrics1Olorun Olodumare Mo dupe lowo re Gbati o fi eri re fun wa Ninu irin ajo wa2Mo siro ojo aiye mi Lati owuro d’ale Iro Jesu nso leti mi Wipe ofo Laiye.3Bi mo ti nrin lona ajo mi Lati wa ogo aiye. Imole Jesu ran si mi Ki nfi ogo aiye (Sile)4Gbati mo wo ogo orun Ayo kun okan mi Gbati mo wo ogo aiye Ekun bo loju mi5Ninu gbogbo ekun ti mo nsu Woli aiye ko mo Aladura aiye ko mo Ariran aiye ko mo6Lehin ekun mi, mo ri eri gba Mo si ri oro gba Eri oro t’aiye ko mo Olorun fi fun wa.7Wakati to t’ emi yio fi Ago ara sile Temi yio lo je opo iya Lodo ariran aiye.8Wakati mbo, t’emi yio lo Si Jerusalemu Lati lo ro ihinrere Ti mo ri gba fun eda.9Jesu na lo je iya fun mi Ki emi si ma sa? Kini igbagbo mi yio jasi? Bi emi ko ba je iya.10Iya pupo t’omo ehin nje ‘Gbati nwon ri eri gba O ye fun mi lati je iya ‘Gbati mo ri edidi.11Okan mi nta nsisiyi Lati fi ihin sile Lati lo rohin edidi Ti mo ri gba fun eda.12Bi aiye pa mi laipe iye ojo Emi mi yio fo lo Sodo Olorun eleda mi To fun mi leri re’Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO ORIN IRIN AJO KINNI TUNE- OLORUN BE TELISimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura5Gborin didun kan ti mo gboOrin Jesu Kristi6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Iwa Mimọ Previous101 · Olugbala mo dupeNext 103 · Keu Nasiry Mennah Alau dau