No. 103 · Orin ỌrunGbọ orin t' awọn Angẹli nkọLyrics1Gbọ orin t' awọn Angẹli nkọ Ni bugbe ti ẹşẹ ko si Wa jẹ ka kọrin na2Wa wọnu awọsama didan Ni bugbe ti ẹşẹ ko si Ilu Ọlọrun ni.3Wo ẹya Israel mejila Wọn wa ni bode mejila Nwọn npe ọ ki o ma bọ4Owo ko le mu ọ de ibẹ Ọmọ ko le mu ọ de ibẹ Ilu Ọlọrun ni.5Wo ilu mimọ ologo didan Nibi ti okun nyi bi digi Ẹşẹ ko si nibẹ.6Orin aiye ko si nibẹ Afẹ aiye ko si nibẹ Ko si iditę nibẹ.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ Revelation 14 : 3Similar hymns168Bi ese mi bale te ite wura didan niOrin Ọrun172Awon eni 'rapada OluwaOrin Ọrun69Sọfun mi Olugbala (2 times)Orin Ọrun133Wo ilu mimo to dara juloOrin Ọrun Previous102 · Ẹda to da mi bọ oNext 104 · Iwọ oşupa Ologo