No. 108 · Orin Ogun Ẹmi ati Igbala · Orin AjindeAjagun ma beruLyrics1Ajagun ma beru E jagun fun jesu E nja fun Jesu Ireti nbe fun Ajagun ma foya Tesiwaju ninu ogun Ireti nbe fun enija fun Jesu2Ireti mbe Igi To ku seba odo Bo ba mgboru omi Yio sin tun soji Gbogbo oku Kristi To ba gbohun Kristi Gbogbo won yio jinde-lojo ajinde3Jesu ti o njagun fun O mo aini re O mo jakadi re ati isoro re Omo ogun ma foya Tesi waju ninu ogun Jesu ti iwo nja fun Yio gba ejo re ro4Eni ku fun Jesu O leni jabo fun Emi re yio duro Rojo re' fun Jesu Jesu to rojo fun Yio si fun ni simi Yio fun laso funfun Ati imope isegun5Se ise iranse re Mase boju wo ehin Ijafata lewu feni boju wehin Isise kan ni iku Isise kan ni iye Omogun ma foya Gbasia ogun soke6Gbe hamo re wo Kojuja si esu Kojuja si ese Won yio sin sa fun o Gbagbele-bu Jesu Fon ipe ihinrere Agbelebu igi ku Yio digi iye fun o. AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryHOLY SAINARY ALORE JESUSimilar hymns7Ẹmi gbe mi bi edidi si ayeOrin Ogun Ẹmi ati Igbala13Ọmọ Ọlọrun nlọ s'ogunOrin Ogun Ẹmi ati Igbala22Igba ogun ni ki Woli jaOrin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ25Itẹdo ilu daraOrin Sioni ati Ijọ Previous107 · Olorun Oba ti ki kuNext 109 · Lodun ti Usia oba ku