No. 109 · Orin Sioni ati Ijọ · Orin Ikede Oro OlorunLodun ti Usia oba kuLyrics1Lodun ti Usia oba ku Mori Oluwa joko lori ite giga Awon Serafu duro loke re Ikokan won niye mefa2Won fi meji nboju Won fi meji nbo ese Won fi meji nfo3Ekini nke si ekeji wipe Mimo-mimo-Loluwa Olorun Awon Omo ogun4Gbogbo aiye kunfun ogo- Oluwa Opo ilekun si nmi Nipa orin Serafu Mimo mimo-loluwa Olorun Awon Omogun5Mo ngbohun Oluwa pelu pee Tani emi o ran Tani o lo fun mi Kole yi araiye pada Sinu ijo Serafu6Oluwa te Ikan re Gigu meji Senu Elisha Lene O so fun pe Lo si gbogbo aiye Lati yi araye pada Sinu ijo Serafu7Kerubu-Serafu-Zion-Ugbo- nla Ijo mimo ati oke wa ni Wa Ore mi kalo gba igbala nibe Wa Ore mi kalo gba iwosan nibe o' wa8Olorun Moses lonpe o o Olorun Lene lonpe O o Si ijo mimo-ati oke wa Wa ore mi etc9Aira nsa lori oke Zion o Iri se lori oke Zion o Nijo mimo ati oke wa Wa ore mi etc10Lohun 'Jenje ni Jesu npe o o Lohun jenje ni Jesu npe o o E wo ijo mimo ati oke wa Wa ore mi etc11Kerubu Serafu (2times) Ijo to nji oku dide Wa ore mi kalo gba igbala nibe Wa ore kalo gba Iwosan nibe o waAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO SAINARY ALORE HOLY CROSSSimilar hymns3Iwo oro Olorun - Ogbon ati oke waOrin Ikede Oro Olorun4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura11Jerusalemu tọrun ti de oOrin Sioni ati Ijọ16Ẹyin ijọ Ugbo-nlaOrin Sioni ati Ijọ Previous108 · Ajagun ma beruNext 110 · Faso alore re Ologo won mi o