No. 123 · Orin Ajinde · Orin AduraWọ to ku ni KalfariLyrics1Wọ to ku ni Kalfari Iwọ to bẹbẹ fun ẹlẹșẹ Ranmi lọwọ nigba aini Jesu gbọ igbe mi.2Ninu ibinujẹ mi Ati ọkan aigbagbọ mi Emi olori ẹlẹșẹ Ngbe oju mi si Ọ.3Ọta lode ẹru ninu Ko si ire kan lọwọ mi Iwọ to gba ẹlẹșẹ la Mo sa tọ Ọ wa.4Awọn ẹlomiran dẹșẹ pe Nwọn si ri igbala gba Nwọn ngbọ ohun ainu rẹ Mu mi gbọ pẹlu.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns99Emi ẹlẹşẹ mo fẹ ibukunOrin Ajinde87Mo ri Ọrọ kan gbọ ninu BibeliOrin Ajinde194Jesu to ku ti yeOrin Ajinde72Ọmọ Alade alafiaOrin Ajinde Previous122 · A! ẹgbin lemi OluwaNext 124 · Itanna nru ewe