No. 87 · Orin Iwa Mimọ · Orin Iyin ati ỌpẹỌkan mi jẹri si igbala rẹLyrics1Ọkan mi jẹri si igbala rẹ Ọlọrun ologo mẹta lailai Gbọ igbe mi, gbọ ẹbẹ mi Ọlọrun ologo mẹta lailai.2Emi yio ma rohin orukọ Rẹ Ọlọrun olubukun ologo julọ Şanu fun mi Ọba ogo Iwọ nikan lemi yio ma sin lailai.3Mimọ mimọ ni Ọ Ọlọrun mi Iwọ ni ẹniti ibi ki ba gbe Sọ ara mi ati ọkan mi Di mimọ ki nle yẹ layanfẹ Rẹ.4Logologo ni işẹ rẹ Ọlọrun Fi ogo işẹ Rẹ han ninu ijọ rẹ Ya ara mi ati ọkan mi Kuro ninu ẹgbin aiye yi.5Iya - simimọ lemi ntọrọ Lọdọ Ọlọrun to mọ bi digi Wo gbogbo awa ijọ Rẹ. Jẹ ka di mimọ bawọn ijọ igbani.6Awọn to ngbe ohun elo mimọ rẹ Sọwọn di mimọ ninu ogo rẹ Şe itọju wa ọba ogo Maṣe jẹki a gbagbe orukọ Rẹ.7Mimọ mimọ nişẹ Rẹ Ọlọrun Ọlọrun ologo mẹta lailai Mimọ lohun elo mimọ rẹ Jẹki awa ti ngbe ohun elo rẹ jẹ mimọ.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura5Gborin didun kan ti mo gboOrin Jesu Kristi6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Iwa Mimọ Previous86 · Mo gbe ori mi le Ọ OluwaNext 88 · Alore Mininah Minah