No. 127 · Orin AduraỌkan mi jẹri si igbala rẹLyrics1Ọkan mi jẹri si igbala rẹ Ọlọrun ologo mẹta lailai Gbọ igbe mi, gbọ ẹbẹ mi Ọlọrun ologo mẹta lailai.2Emi yio ma rohin orukọ Rẹ Ọlọrun olubukun ologo julọ Şanu fun mi Ọba ogo Iwọ nikan lemi yio ma sin lailai.3Mimọ mimọ ni Ọ Ọlọrun mi Iwọ ni ẹniti ibi ki ba gbe Sọ ara mi ati ọkan mi Di mimọ ki nle yẹ layanfẹ Rẹ.4Logologo ni işẹ rẹ Ọlọrun Fi ogo işẹ Rẹ han ninu ijọ rẹ Ya ara mi ati ọkan mi Kuro ninu ẹgbin aiye yi.5Iya - simimọ lemi ntọrọ Lọdọ Ọlọrun to mọ bi digi Wo gbogbo awa ijọ Rẹ. Jẹ ka di mimọ bawọn ijọ igbani.6Awọn to ngbe ohun elo mimọ rẹ Sọwọn di mimọ ninu ogo rẹ Şe itọju wa ọba ogo Maṣe jẹki a gbagbe orukọ Rẹ.7Mimọ mimọ nişẹ Rẹ Ọlọrun Ọlọrun ologo mẹta lailai Mimọ lohun elo mimọ rẹ Jẹki awa ti ngbe ohun elo rẹ jẹ mimọ.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns179Ninu aginju awe mo wa yiOrin Adura122A! ẹgbin lemi OluwaOrin Adura3Iwo oro Olorun - Ogbon ati oke waOrin Adura143Faso alore re Ologo wo mi oOrin Adura Previous126 · Nitori Oluwa mo fi ile mi silẹNext 128 · Alore Mininah Minah