No. 128 · Orin Awon to ntoro omo · Orin AduraAlore Mininah MinahLyrics1Alore Mininah Minah Missiah ẹri Zion Yara fun mi lọmọ bi Jọwọ fun mi lọmọ bi Ki nle ye șe iye meji.2Awọn ọmọ ologo ti monri Lori oke ẹri Zion Bi nko ba bi ninu wọn (2 times) Emi yio kanu pupọ3Baba jọ fun mi ni ẹbun ini mẹta Ti eşu fi nri ọrọ sọ simi Owo ọmọ Ati agbara ẹmi.4Iran didan ni emi ntọrọ Lọdọ Ọlọrun mi Fun mi ni agbara awẹ ati agbara adura Ki nle fi șegun eşu ati ẹșẹ.5Baba mu iri rẹ bale mi Fun mi lọpa irin Ki nle fi ma șakoso larin orile ede Ki gbogbo aiye le mọ iwọ nikan.6Ọlọrun nlo ipa lode aiye Dragoni si nru ipa na Ọlọrun ẹlẹda mi ẹlẹda gbogbo Woli Joti ọdọ ijọsin yi șe apa Satani.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns176Asia Mininah duroOrin Awon to ntoro omo19Leti bebe JordaniOrin Awon to ntoro omo26Iwaju ite aanu1990 · Orin Awon to ntoro omo73Kọrin iwọ agan ti ko biOrin Awon to ntoro omo Previous127 · Ọkan mi jẹri si igbala rẹNext 129 · Iwọ ọmọ mi, iwọ ọmọ mi