No. 132 · Orin Ekun Alore · Orin AduraNibo mare o Baba miLyrics1Nibo mare o Baba mi Nibo ni marin si laiye o Aiye pa Pupo Awon ayanfe re o Baba Nwon si nsariya le won lori2Bi olododo ti nku nlo Ko si eni to ranti won Nibo ni mare o Nibo ni mare o Baba3Wo bi itana lili ti nku ni pepe Igi osusu lo nfi na su won Awon elese para po Nwon si nba awon ayanfe jagun4Iku feni ibi sile Olododo lo mbaja Nibo ni ma re o 2ce Baba Baba5Ti Oluwa nile ati ekun re Aiye ati awon ohun inu re Esu si mba mi ja lori ile Baba mi o Gba oro yi ro o 2ce o. Baba.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryEXMINARY SAINARY ALORE JESU ORIN MIMOSimilar hymns33Ile aiye nyi biri biriOrin Ekun Alore109Mo fi duru mi kọ igi willoh (2ce.)1964 · Orin Ekun Alore120Adaba ẹri mi o, nibo lore o ?Orin Ekun Alore145Okan mi nse aferi orunOrin Ekun Alore Previous131 · Mu eni irapada waleNext 133 · Wo ilu mimo to dara julo