No. 142 · Orin AduraOlorun Oba ti ki kuLyrics1Olorun Oba ti ki ku Olorun Oba ti ki darugbo Pin fun mi ninu aiku re o 2ce2Sainary Alore ti ku Mennary Alore ti ku Gba oro mi ro fun lodumare, 2ce3Funfun gbo loro re Oluwa Oro Olorun ki ku Jo Olorun furugbin re sokan mi4Pattracki Alore ti mo ri To duro seba odo ti nsan Mu mi pe ninu ewa Alore o 2ce5Adaba to faso wo awon Alore Ti won nkorin losan ati loru Faso siry alore wo mi o Baba6Aso emi tawon Alore fi nkorin Ahon happu tawon Alore finyin o Olorun Baba faso emi orun womiAmin.About this hymnWritten byProphet MennaryEXMINARY ALORE C&S SAINARY ALORE JESUSimilar hymns143Faso alore re Ologo wo mi oOrin Adura27Has Siry mini Center Alau1957 · Orin Adura45Iro didun kan sọ o AloreOrin Adura2Bi o se da mi si Oluwa Orin Adura Previous141 · MARIA MIMO -wo omo re oNext 143 · Faso alore re Ologo wo mi o