No. 141 · Orin AjindeMARIA MIMO -wo omo re oLyrics1MARIA MIMO -wo omo re o Lori Igi Agbelebu Mase je ki ya pupo o Siri Elory Maria Alau2Ongbe - ngbe mi o Otin kikan laiye fun mi Itura ni mo fun aiye o Aiye kan mi mo Igi oro3Igi iye ni mo mu fun aiye o Aiye kan mi mogi iku Eli Eli Olorun mi Baba mi ma ko mi o4Mo de lati laju afoju Omo araiye tuto soju mi Mode lati tu onde sile Sekeseke laiye fi de mi5Jesu ki gbe ni wahale kefa Aso tempili gbogbo faya Aira nsan isele se Awon oku mimo si jinde6Jesu mimo so iran mi o Gbati iwo bade ijoba re Lese Agbelebu ni mo wole , Jimi dide omo Mary. AminAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryEXMINARY ALORE C/S SAINARY ALORE JESU Jesu on the CrossSimilar hymns194Jesu to ku ti yeOrin Ajinde83Awa ọmọ kekekeOrin Ajinde130Mo ti gbe agbelebuOrin Ajinde195Jesu ti jinde mojo moyoOrin Ajinde Previous140 · Mase tori Mamoni alaistitoNext 142 · Olorun Oba ti ki ku