No. 15Ara eje ka loLyrics1Ara eje kalo - Ara eje kalo Si ile Olorun wa Yio fun wa logbon Yio fun wa loye Yio fi ona orun han wa2Esu si ngbogun Ni gbogo orile ede O mba omo Olorun ja Tera mo igbagbo re Ki iwo bale segun - esu ati ese3Aiye lajo wa Orun ni ilu wa Oye ka mo ona orun Bi o ba gba Jesu gbo Yio ko wa leko orun Yio fi ona orun han wa4Buburu ko lere Iborisa ko lere Fun awon alaigbagbo Tera mo igbagbo re Pa ofin Jehovah mo Gbana Baba yio fe o5E mase wo aiye Orun on aiye a fo lo Beni Oluwa nso Eniti o ba gbagbo Yio ba awon ayanfe pe Lori ite Olorun6Mori pupo awon asegun Bi won ti nkoja lo Si apa ila orun Nwon nkorin simi pe Ki mura je ka lo Si ile Olorun wa.7Ara eje ka lo - Ara eje ka lo Si ile Olorun wa Yio fun wa lebu emi Yio fun ni alore Yio fi oro orun jiki wa. AminAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO FRIDAY Evening 17/5/57 The Harmmar RomissionallyAlbumAriamasalauEmisanmi Mennary Ajimuda, Ojo Ayo Mennary Ajimuda +39 hymns Previous14 · Bi wakati adura ti n sunmoNext 16 · Awọn kan ntẹle eşu