No. 16 · Orin Sioni ati Ijọ · Orin Ikilọ

Ẹyin ijọ Ugbo-nla

Lyrics

Chorus

Ọba meji kole jẹ - Ni ilu Ugbo-nla Ki Elisha nikan jọba Ni aiye agiju yi.

Chorus

Ọba meji ko le jẹ, etc.

Chorus

Ọba meji ko le je, etc.

Chorus

Bo ba ṣepe bẹ na ni Ki nwọn wolẹ fun aṣaju wọn Ọba meji ko le jẹ Ni aiye ẹlẹtan yi.

Chorus

Oṣupa ko pe meji Ẹjẹ ka fori balẹ Ki Elisha nikan jọba Nilu Ugbo-nla.

Chorus

Ẹjẹ ka farabalẹ Ka sin Jesu Oluwa Ki Elisha nikan jọba Ni ilu Ugbo-nla.

Chorus

B' ọba meji ba dide Awọn ewe ko le gba Ki LENE nikan jọba Pẹlu awọn osogbe rẹ.

Amin.

About this hymn

Written by
Prophet Mennary

ORIN MIMỌ SAINARY ALORE

Similar hymns

Keep these hymns alive

Free to use. If these hymns have blessed you, a gift towards the mission helps keep them coming. Thank you.

Bank name
Ecobank
Account name
Wokeboy Brand
Account number
8120835077