No. 163Ranti ẹlẹda rẹ Lyrics1Ranti ẹlẹda rẹ Nigba ewe rẹ o e Nigbati ọjọ iku ko ti de A! Ranti ẹlẹda rẹ Nigba ewe rẹ o2Sunmọ Ọlọrun rẹ Nigba oro yi o e Nigbati ọjọ aisan rẹ ko ti de o A! sunmọ Ọlọrun rẹ Nigba owurọ rẹ o e3Ṣe iṣẹ fun Ọlọrun rẹ Nigba owurọ rẹ o e Nigbati Olukore ko ti de o A! Ranti ẹlẹda rẹ Nigba Owurọ rẹ o eAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Iwa Mimọ20Romicinah - Mary Alau-Dauher1956 · Orin Ọrun ati Iye Ainipẹkun21Mo ngbọ ọrọ edidi ọrun 1957 · Orin Woli, Iran ati Ẹmi Mimọ Previous162 · Jesu olori ijọNext 164 · Ọlọrun yan mi si woli