No. 173Jesu to ku ti yeLyrics1Jesu to ku ti ye (2x) Gbo orin didun ti awon angeli ko pe Jesu to ku ti ye2Maria lo si iboji o ri angel meji Won so fun pe Jesu toku ti jinde Jesu to ku ti ye3Imole Ajinde tan Eru ba awon Oluso Won wariri won dojubole, Nigbati Jesu jinde4Oju ti awon asefe Oju ti awon elegan Jesu ti jinde o lo si Galili Oju ti awon elegan5Ayo onigbagbo kun Awon angeli ho ye Nigbati olorun ti ji Olugbala Dide onigbagbo ti ye6Ireti mbe fun eni to gbe agbelebu Jesu Sa gba Jesu gbo Bi Jesu ti jinde Beni iwo yio jinde.AminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous172 · Eli o Omo SioniNext 174 · Jesu ti jinde mojo moyo