No. 166 · Orin Idande · Orin AduraOlorun igbalaLyrics1Olorun igbala Olorun iwosan Olorun igbala - wa gba mi2Wo bawon abinu iku mi Ti nkorajo simi Won mbere nigba wo Lemi o ku.3Won mbere nigba wo Toruko mi yoo run Won mbere nigba wo ni Irawo mi o wo4Olorun igbala Olorun iwosan Olorun igbala Wa gba mi5Awon ti nse ota mi Ni pa eri re to fun mi Won si po pupo Ju iru ori mi lo6Won nta ofa si mi Won nran ategun si mi Won nran aisan si mi Ki emi ba le ku Olorun igbala Olorun Mose Olorun Elisha Iwo ni apata mi.7Olorun Igbala Olorun Iwosan Ma jeki emi Pada to esu lehinAmin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN ADURA Mennary ALore Jesu John 5:1-8Similar hymns35Alore Ọlọrun Simiro1957 · Orin Idande209Romissionally mi o alau miOrin Idande111Bi mo ti nnaga nwa ogo ọrunOrin Idande220Eri ti mo ri ni mo nlo Baba1955 · Orin Idande Previous165 · Olorun mi mo bebe niNext 167 · Mennah eri Oluwape