No. 35 · Orin Ajinde · Orin Igbagbọ ati ItunuMo ri Ọrọ kan gbọ ninu BibeliLyrics1Mo ri Ọrọ kan gbọ ninu Bibeli Nwọn nsọrọ na pe, Krist jinde Bi o ba ṣe pe Otitọ ni iwọ jinde Wa fi ara Rẹ han mi ki nle gba Ọ gbọ.2Nwọn nsọrọ Ajinde fun iranṣẹ rẹ kan On ko si gba Ọ gbọ pe O ji dide On si bere ami O si fi ami han Bi o ba jẹ pe O jinde Jọ fi ara han mi.3Ro ti ọrọ ti O so Fun awọn Apostle Wipe ẹnito kankun4On la o si fun Ẹni to ba bere On yio şi ri gba Mo bere Ajinde Rẹ Jẹ ki nle ri Ọ.5Pupọ awọn agba Ni ko ranti rẹ Awọn ọmọ pupọ Ni ko gba Ọ gbọ Mo ti gba Ọ gbọ pe Iwọ ji dide Fi agbara Ajinde Han awa Ojiṣẹ Rẹ.6Jesu Onirẹlẹ Ọmọ Ọlọrun Alanu Olufẹ Gbọ igbe ọmọ Rẹ Ma ro ti ẹṣẹ mi Fi ara han mi Ki nle sin Ọ titi De opin ẹmi mi.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns2Bi o se da mi si Oluwa Orin Adura15Iro didun kan sọ o AloreOrin Adura19Kọrin iwọ agan ti ko biOrin Ọmọ, Ẹbi ati Ibukun30Awa ọmọ kekekeOrin Agbelebu ati Irapada Previous34 · Jesu awa ti duro toNext 36 · Ninu ajinde ekini