
No. 175
Mimo mimo loro Olorun, O f'oro re senu Elisa
Lyrics
Chorus
Aginju igbo di ilu Ogo Holy O Holy O.
Chorus
Lati owo woli Elisa Holy O Holy O.
Chorus
Fun gbogbo awon onigbagbo Holy O Holy O.
Chorus
To so Aginju Igbo di ilu Ogo. Holy O Holy O
Chorus
Lati Owo Woli Elisah O Holy O Holy O.
Amin
About this hymn
- Written by
- Prophet Mennary
Orin mimo Sainary Alore Tune: Iran Orun Iwo tileru to