No. 174Jesu ti jinde mojo moyoLyrics1Jesu ti jinde o Mojo moyo Angeli bami gbe ayo mi ga Jesu ti jinde o mojo moyo Angeli bami gbayo mi ga2Wo awon adaba ninu sama Won fiye nwo ara won, won njo Nwon nkorin ayo Ajinde Angeli bami gbayo miga3Angeli meji leti boji Ogo won ntan yi boji ka Awon Olusi ri imole won Niberu won dojubole4Maria sare lo siboji O ri Olugbala nibe O sunmo Jesu o pe Rabbi Angeli bami Gbayo mi ga5Eli eli lori oke ipe dun ara san Awon elese dojubole Nigbati Jesu jindeAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous173 · Jesu to ku ti yeNext 175 · Mimo mimo loro Olorun, O f'oro re senu Elisa