No. 177 · Orin Ikilọ · Orin IsegunMennah rasion manna alauLyrics1Mennah rasion manna alau Mennah.rasion and tender Mennah rasion against ibaje aiye Mennah aresting leader aiye2Ji gbogbo awon to sun Fi oro Kristi han fun won Kiri yi gbogbo igberiko ka Fon ipe si elese.3Ru agbelebu Kristi kiri Fi da isin eke lebi Fi han fun gbogbo alaimokan Pe Kristi lo ye ki a tele.4Bi iwo ba nsin nitoto Emi o fun o lagbara Lati da gbogbo isin eke lebi Enu won ki yio le ran O.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO SAINARY ALORESimilar hymns167Mennah eri OluwapeOrin Ikilọ139Keu Nasiry Mennah Alau dauOrin Ikilọ117Krist ti oke ọrun la ọna igbala wa sode aiye1958 · Orin Ikilọ161Ni irele ni iteribaOrin Ikilọ Previous176 · Asia Mininah duroNext 178 · Oju Mennah mi, oju Adaba mi