No. 139 · Orin Ikilọ · Orin IsipayaKeu Nasiry Mennah Alau dauLyrics1Keu Nasiry Mennah Alau dau Soro ipile aiye fun mi Dau Nasiry Mennah alau dau Adamu lo ba aiye je o2Ofin mimo Olorun fun wa Efa mu Adamu rufin na Olorun le won kuro ninu ogba O soro egun le won lori3Nipilęsę ibere aiye Angel lojise Olorun Nwọn ba awọn Obirin aiye da lo Olorun le won kuro laiye4Dau Nasiry Mennah alau dau Soro edidi meje Keu Nasiry Meneah alau dau Adamu lo mu iku wa o5Gbogbo lala ta nse laiye Adamu ko je ka jere re Lala koko-kęką ta nse Adorin odun lojo aiye wa mo6Eni erupę ni Adamu nse Yio pada s'erupe Je ka ko ara Adamu sile Ka gbe ara Kristi woAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO SAINARY ALORE JESU C/SSimilar hymns177Mennah rasion manna alauOrin Ikilọ93Enia ti a bi ninu ObinrinOrin Ikilọ129Iwọ ọmọ mi, iwọ ọmọ mi1964 · Orin Ikilọ167Mennah eri OluwapeOrin Ikilọ Previous138 · Olorun OlodumareNext 140 · Mase tori Mamoni alaistito