No. 18 · Orin Adura · Orin IsegunMo fi ija mi fun OlorunLyrics1Mo fi ija mi fun Olorun Mo fi oran mi le lowo Mo fi gbogbo ejo mi fun Pe ko gbaro fun mi2Bi aiye nbu mi nko ka si Bi won nlo mi nko yanu Ife Kristi lo se mi be Ti nko ba ko oro aiye si3Wo egan aiye lara mi Tori Kristi nko je ja Baba to nwasu pe kin ma se ja Gba ejo mi ro fun mi.4Gbesan mi Oluwa Olorun Lara awon ota mi Jeki enu mi gboro wa yi Lara awon ota mi5Iwo ni ki a gbe ga Gbe ogo Re ga lara mi Ohun ti o se edun fun okan mi Jeki nle ni wayi6Tori Re ni mo se fi ejo sile Mo se fi epe sile Iwo to ni pe ki nma se ja Bá ọta mi já fún mi.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO SAINARY ALOREAlbumAriamasalauEmisanmi Mennary Ajimuda, Ojo Ayo Mennary Ajimuda +39 hymnsSimilar hymns65Maṣe ba mi rojọ Oluwa miOrin Adura98Bi o ti nlo mi nlọ yi OluwaOrin Adura3Iwo oro Olorun - Ogbon ati oke waOrin Adura97Ero mi da rudu-ruduOrin Adura Previous17 · Ranti ẹlẹda rẹ Next 19 · Leti bebe Jordani