No. 17 · Orin IkilọRanti ẹlẹda rẹ Lyrics1Ranti ẹlẹda rẹ Nigba ewe rẹ o e Nigbati ọjọ iku ko ti de A! Ranti ẹlẹda rẹ Nigba ewe rẹ o2Sunmọ Ọlọrun rẹ Nigba oro yi o e Nigbati ọjọ aisan rẹ ko ti de o A! sunmọ Ọlọrun rẹ Nigba owurọ rẹ o e3Ṣe iṣẹ fun Ọlọrun rẹ Nigba owurọ rẹ o e Nigbati Olukore ko ti de o A! Ranti ẹlẹda rẹ Nigba Owurọ rẹ o eAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957AlbumAriamasalauEmisanmi Mennary Ajimuda, Ojo Ayo Mennary Ajimuda +39 hymnsSimilar hymns93Enia ti a bi ninu ObinrinOrin Ikilọ63A! iwọ igi yi : A! igi yiOrin Ikilọ7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ124Itanna nru eweOrin Ikilọ Previous16 · Awọn kan ntẹle eşuNext 18 · Mo fi ija mi fun Olorun