No. 225Ha! enyin omo Ara aiyeLyrics1Ha! enyin omo Ara aiye Ki lohun ti mo se nyin? Ti e fi nwa ibi fun mi2Ha! Enyin omo enia Ki lohun ti mo se nyin Ti e fi nbere eje mi3Mo nso otito fun aiye Aiye nso otito di eke Nwon ko mo oro Olorun4Gbati imole wa si aiye Ara aiye ko imole Nwon gbe okunkun mora5Wa Olodumare Ki lohun ti mo se Ti ara aiye fi nwa emi mi6Lojojumo nwon nwa Emi mi lati gba Nwon si ibere eje mi7Olodumare gbo Bi mo ba se si aye Jeki nwon le pa mi8Mo pe oke ati ile Se eleri larin wa Pe emi ko se aye Ipade wa dorun9Bi omo ara aiye pa mi Laije pe mo se won Baba yo ja fun miAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous224 · Ogo, Ogo ogo pipe ti OlorunNext 226 · Kemi to ri eri yi