No. 226Kemi to ri eri yiLyrics1Kemi to ri eri yi Mo ri ite kan loke Mo ri gbogbo Woli Joko lori ite kan Adaba mimo kan Si nti oke orun wa On nsoro orun fun won Ibi isimi ikehin2Woli akobere Titi de isipaya Si fi ipe senu won Nwon nsoro ite Olorun Ati ijoba re Ti awon omo Re yio ni Bi nwon ba le gbagbo Ti won ni ite na.3Nwon nso ohun t'oye Ki a ma se laiye yi Mo gboro ofin Olorun Ninu ipe ti nwon nfon Mo gbo pe na Ati oro ti nwon nso Mo dara po mo won Ninu emi Oluwa.4Mo wa ninu emi Mo si ri Woli kan Nti ori ite sokale O fun mi ledidi Oro Olorun Ti nse eri otito Oro ihinrere Ifihan otito.5Emi si nmu mi rin Yi gbogbo aiye ka Lati kede fun aiye Pe ki nwon pa ofin mo O nso fun mi Nipari eri yi Emi o se o loba Ati alufa fun mi.6Aiye yio ba nyin ja Nwon yio fi nyin sesin Nwon o le nyin jade Ni Sinagogu won Ema beru So otito de oju iku Ade iye nbe loke Ti nse ayanfe miAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneJERUSALEMU TI ORUN Previous225 · Ha! enyin omo Ara aiyeNext 227 · Tori mi ati ihinrere