No. 227Tori mi ati ihinrereLyrics1Tori mi ati ihinrere E lo so ti irapada Awon onise re nke amin: tire ni gbogbo Ogo Nwon nso tibi, tiya,ati iku Ife etutu nla re Nwon ka ohun aiye sofo Ti ajinde on ijoba re.2Gbo, gbo, ipe ti Jubeli O ndun yi gbogbo aiye ka Nile ati loju okun, a ntan ihin igbala Bi ojo na ti nsumole Ti ogun si ngbona janjan Imole ila orun na, yio mo larin okunkun.3Siwaju ati siwaju, la o ma, Halleluyah gbo Ijo ajagun yio ma yo; pelu awon Oku mimo Afoso won ninu eje re Duru wura won si ndun Aiye ati orun dorin po Nwon nko orin isegun4O de eniti a nwa ona re Emmanuel na de Emmanuel to de ade Oluwa awon mimo Iye imole ati ife Metalokan titi lai Tire ni ite Olorun ati odo agutanAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous226 · Kemi to ri eri yiNext 228 · Awon Kan nrope Olorun ko si o