No. 248Ejeki a fi iyin fun OluwaLyrics1Ejeki a fi iyin fun Oluwa Enyin orile ede A o fi ope fun Oluwa To mu wa ri ojo oni e2Pupo ninu awon orile ede Lo wa ninu aisan A ko le ka awon enia Ti iku npa lojojo3Emi o ma yin Oluwa 'Gbati mo wa laye Emi o korin mimo si Olorun eleda mi4Alaye ni io ma yin Oku kole yin O Ngo korin mimo si O Olorun tó nso mi5Gbogbo enyin orilę ede Eje ka yin Oluwa To nso wa nigabti a ba sun Ni wakati oru.6Eje ka fi iyin fún Oluwa Enyin omo enia Korin mimo si odo Aguntan Nigabti o wa laye.7Jeki ateriba fun Olorun Fi ijo ati orin yin Yin Oluwa pelu okan funfun Yin pelu atewo.8E jeka fi iyin fun Oluwa Gbogbo orile ede Eje ka korin mimo si Olorun eleda wa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN IYIN ATI OPE PSALM 150 Previous247 · Oba mimo jowo dakun ye oNext 249 · Aisan kan wa lara okunrin