No. 25 · Orin Sioni ati Ijọ · Orin Ogun Ẹmi ati IgbalaItẹdo ilu daraLyrics1Itẹdo ilu dara Awọn ọmọ ilu kodara Nwọn ba ẹgbẹ oṣo ṣe pade Lati padaba ẹri. Ẹ lọ ronu, ẹ lọ ronu Bẹni Adaba nsọ fun wọn.2Itẹ ti Adaba nlo Laiye ko aja ọdẹ si Nwọn ran aja ọdẹ wọn Lati mu adaba ẹriChorusBẹni, etc.3Ibori Woli nfẹ lẹlẹ Eṣu ri eyi o binu O nawọ lati mu wọn Adaba ẹmi gbẹ wọn foChorusBẹni, etc.4Igi ororo Ọlọrun Ẹ ma ṣe ke lu-lẹ Ẹ ni ke igi ororo Ko le ri imọlẹ Ọlọrun.ChorusBẹni, etc.5Igi ajara Ọlọrun Ki ẹ ma ṣe ke lulẹ Ẹni ke igi ajara Ko le ri Mana ọrun jẹ Ẹ lọ ronu (2 ce.) Ẹnyin oṣo oke Sioni.6Lenẹ igi ororo Lenẹ igi ajara Ẹ maṣe gbimọ ibi si Kẹ maṣe ba lenẹ jaChorusOluwa gbogun ti awọn ọta To gbiro bi si lenẹ Oluwa gbogun ti awọn ọta Ti o gbogun ti ọba Sioni.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMỌ SAINARY ALORESimilar hymns4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura7Ẹmi gbe mi bi edidi si ayeOrin Ogun Ẹmi ati Igbala11Jerusalemu tọrun ti de oOrin Sioni ati Ijọ13Ọmọ Ọlọrun nlọ s'ogunOrin Ogun Ẹmi ati Igbala Previous24 · Ajaga Kristi ti mo ruNext 26 · Adaba ẹmi nsọkun ẹdun Hirrylow, Hirrylow