No. 149 · Orin Iyin ati Ọpẹ · Orin Sioni ati IjọAsia Mininah duroLyrics1Asia Mininah duro Ombo wa ni ilu Eri Kristi so ibanuje di ayo E je kayo o tori Olorin oro2Ile alaileso di eleso Ile ti ko lerun di elerun Wo bi iwefa ti di Ominira Iyanu ni ise Re Olorun.3Oluwa mu egan wa kuro O so orin ofo di Orin ayo Nitori Mininah to fun wa Ngo layo tori Olorin oro.4Awon pansaga bere omo Oluwa fun won loke Eri O bo aso ofo won kuro Iyanu ni ise re o Oluwa.5Kristi so ekun wa di erin O so ikanu wa di Orin ayo Gbogbo ekun aro ti mo sun MIninah ti so di Orin ayo fun mi6Ile alailogo di Ologo Wo bi eni egan ti di eni ire Ko si ohun ti Oluwa ko le se E je ki ani igbekele si Olorun7Eniti nsokun omo di elerin Iwo igbala wa ni Kristi gbega To ri Mininah to fun wa bi E je kayo o tori eda titun.Amin.About this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO Sainary AloreSimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo TireOrin Adura5Gborin didun kan ti mo gboOrin Jesu Kristi6Geography ọrun ti Ọlọrun fi fun wa1959 · Orin Iwa Mimọ Previous148 · Wo gbogbo egbe Woli to padeNext 150 · Mennah rasion manna alau