No. 250Ja! Jehovah BabaLyrics1Ja! Jehovah Baba Ja! Jehovah o Iwo to mu omo gbawe Laini iye ojo2Ki awon ti npa omo Ma ba le pa omo Ki awon ti nba oyun je Ma le ba oyun je.3Ki awon omo ti esu de Ba le wa sode aiye Ki obirin to yagan Le di olomo.4Omo se ise ti o ran Baba Omo se ise to ran Alaisan ri iwosan Agan si di Olomo5Alaisan ri iwosan Agan si di Olomo Gogbo won si gbagbe Olore owuro6Anu se mi Baba Ekun bo loju mi Ja! Jehovah Baba Ma jeki ngba gbe re.7Iwo to mu iwosan wa Sodo awa ojise re Mo fi ope fun O Iyin ni fun O.8O fi Omo fun Elisha Ki o fi fun agan obirin O mu ki ojise re Tu awon ti esu de9Awa gabadura pupo L'aini iye ojo A si fi awe nje Ara wa ni iya.10Bawo ni ki nti se? Olorun Oluwa Se rere fun Omo re Mo mbe o Oluwa11Baba fun wa logbon Baba fun wa leri Jowo fun wa lomo Ki esu ma yo wa.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO NINU ISE IRANTI Previous249 · Aisan kan wa lara okunrinNext 251 · 'Gbati mo rı osupa