No. 259Iran didan to han simi loke eriLyrics1Iran didan to han simi loke eri Mo ri pupo eda orun Nwon fi ipe si enu won Mo ngbo oro ipe won Pe ka fi ara bale2Adaba mimo nfo loju sama eri Nwon fi okun orin senu won Lati fifun Alore gbogbo akorin mura Lati korin orun3Gbawo lemi o pe-Bi awon Alore orun Nwon fi ojojumo nkorin iyin Si Olorun eleda won Ko si eke lenu won Ko si etan ninu won.4Iran didan to han simi lati oke wa Mori pupo awon ite Ti awon eda orun wa Nwon nrohin ayo fun mi To wa ni paradise5Aiye ko ladun kan Gba mo ri ran orun Okunrin ati obinrin Jeka gba Kristi gbo Kale bo sinu ayo Ati isimi orunAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryORIN MIMO EMI OLORUN. IRAN ORUN Previous258 · Di oro Oluwa muNext 260 · Getsemane nso simi