No. 260Getsemane nso simiLyrics1Getsemane nso simi Ati gbobo awon aguntan re Pe tani Woli na? To lo sí golgata Pe ni Woli na? To lo sibi agbari2Mo ngbo oro orin orun Wipe Tani Woli na Ti a fi oko gun legbe Pe tani Woli na To fo itegun esu3Mo ngbo orin titun kan Wipe tani Woli na To lo sorun fun wa To fun wa lajinde To ran emi re sı wa Getsemane ni Woli na4Getsemane ni Olugbala ti mo mo To lo si orun giga On si tun pada wa Gege bi owara ojo Sori awọn Aposteli5Tani Woli na Ti yio bo ide esu fun wa Tani Okunrin na Ti yio gba mi kuro Ninu adagun esu To fi npa awon ewe6Adagun Omi ti Esu tu si Maria Nipa ibi Getsemane Tani okunrin na? To ran Maria lowo Getsemane ni nse7Mo ri ile nla kan To duro lori oke Tani nse ile na? Mahamadu ni Emi Getsemane Lo duro lori ile na8Emi Getsemane Wa ninu Mahamadu Mo duro lori re Mo ra gege bi adaba Lo si ile ti mo fe Ati okan ti mo fe9Getsemane ti de Gbogbo irokeke de opin Igbogun aiye de pin Ibaje aiye de opin Tani fo ese aiye nu Getsemane ni mo mo10Emi ni ilekun Beni Getsemane nso Mo wo inu aguntan mi Mo fun won lagbara Mo si se won logo Bi Baba ti se mi11Baba bere ise Mo wa pelu Baba mi Emi se eketa wa Nipa ise Ajinde Aguntan pelu mi Ipinle merin duro12Ipinle merin yi To dara to si daju Nibe logbon gbe wa Nibe ni Suru wa Nibe ni Eri wa Nibe ni oro wa13Osuwon meji yı To yi gbogbo aiye ka Tani le mo opin re Tani le mo Ibu re Emi Getsemane lo mobi o tiriAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous259 · Iran didan to han simi loke eriNext 261 · Goke iwo emi mi