No. 264Jeki nle pelu won OluwaLyrics1Jeki nle pelu won Oluwa Jeki nle pelu won Gbogbo egbe Woli to ti gbade loke Jeki nle pelu won2Jeki nle dabi won Jehovah Jeki nle dabi won Gbogbo awon akorin to ti korin ododo Baba kami mo won3Jeki nle gbade bi won Jehovah Jeki nle gbade bi won Awon Ojise re to ti se ise ododo Jeki nle gbade bi won4Jeki nle dabi won Oluwa Jeki nni igbagbo bi won Gbogbo awon oluko, ti o ti se ise ododo Jeki nle dabi wonAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous263 · Gbo, gbo, iwo ileNext 265 · Ifi ori ti de opin