No. 265Ifi ori ti de opinLyrics1Ifi ori ti de opin Lona igbala ti awa nrin Bi iwo ko fi ori ti de opin Iwo ko le ni igbala2Egan pupo lo wa Lona Kristi ti anrin Bi awa ba le fi ara da iya A o gba ade ni ikehin.3Esin pupo lo wa Lona igbala ti a rin Iya pupo lo wa lona na Bi mo ba le fi ori ti de opın Emi yio ri igbalaAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous264 · Jeki nle pelu won OluwaNext 266 · Ko si eda to mo