No. 270E wo gbogbo ojise aiyeLyrics1E wo gbogbo ojise aiye Ti nkigbe tantan ninu wahala E wa gbo ohun Ojise orun Ti nkorin isegun yin Kristi logo2E wo awon akorin aiye Ti nhu iwa igberaga E gbo ohun akorin orun Ti nkorin ajinde, Kristi lojo3Gogbo enyin Serafu aiye To nhu iwa agberaga lojojo Ewa wo Serafu orun Ti nkorin ogo iyin Oluwa4Mo gbo ohun Oluwa to nso O nwipe imole aiye lemi Enyin to nrin lokunkun Ewa ngo fun nyin ni imole5Enyin omo ti o sina E wa bere oju ona igbani Enyin omo apehinda E wa ngo dari ese ji yinAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous269 · Aran ori mi, Aran inu miNext 271 · Ona ewo lemi o rin si Oluwa?