No. 271Ona ewo lemi o rin si Oluwa?Lyrics1Ona ewo lemi o rin si Oluwa? Nitori ipe ti ofi pe mi Kilohun ti emi o se Olorun? Ninu ona ti iwo fi han mi Ara aiye nko ipe re Oluwa A! Anu se mi.2Awon kan ntele ona Korah Nwon si nsure sinu isina Balamu Nwon ko oro otito Olorun A! Anu se mi3Awon kan wa ninu ife Kaini Nwon nfi ife pa omo enia Nwon si wa ninu ijo Judasi A! Anu se mi4Ona ewo loso yio rin? Lojo idajo Oluwa Ona ewo laje yio rin? Lojo igbesan Olorun Bi aiye ti nko otito ti Olorun Orun yio ko ibaje.AminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous270 · E wo gbogbo ojise aiyeNext 272 · Dide, dide Dide iwo irun ori mi Seife Oluwa