No. 275Ninu aginju ti mo wa yiLyrics1Ninu aginju ti mo wa yi Mo si ri iranlowo Oluwa Mo si mbe Oluwa mi lojojumo Ko mase gba abo re lori mi2Nigbati Oluwa wa lodo mi Kilohun ti emi beru? Bi mo ba le pa ofin Baba mi mo Nko ni foya ogun esu3Ogun esu dide si onigbagbo Esu mo pe on ko le segun O si pada sodo omo kekere O si mba won ja lojojumo4Ebe ni mo nbe Olorun mi Ko fun wa lagbara lori esu Ninu aginju Eri ti a gbe wa yi Mase jeki a ri ohun ibaje kan.5Mo nreti isodomo mi Lodo Oluwa Olorun mi Ninu aginju mimo ti a ngbe yi Ni Oluwa yio ti se mi logo.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneJEKALAYO NINU JESU Previous274 · Omo Olorun gbo ohun AloreNext 276 · Eda nla kan lesu wa