No. 276Eda nla kan lesu waLyrics1Eda nla kan lesu wa Nigbati Olorun da O fi si arin Ogba Eden, O fi okuta se ibora2Wura ni ise ilu re Ati awon fere Oruko re ni Kerubu ti a bo Baba si tun gbe kale3Esu wa loke mimo O nrin soke o rin sodo Larin awon okuta ina Nitoripe on lewa4Esu pe lona re Lojo ti Olorun da Titi a fi ri aisedede lowo re Nitoripe opo owo re5Iwo Kerubu ti a bo Kuro loke mimo yi Okan re ti gberaga pupo Nitori ewa re6O ba ibi mimo re je Nipa arekereke re Nipa aisedede owo re Baba yio le o jade7Ezekiel ti ri o Lori kokanlelogun Bere lese karundinlogbon, Iwo yo mo pe o ti ri o8Mu fila esu kuro Si ade kuro lori re Titi Maria yo fi robi Omo Alade Alafia.9Baba yo bi esu subu Yio le kuro lori ite Gbogbo Angeli yio si ma yo Nigbati esu yo subu.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryEzekiel, 28:13-19 Previous275 · Ninu aginju ti mo wa yiNext 277 · Ami nla kan si han lorun