No. 277Ami nla kan si han lorunLyrics1Ami nla kan si han lorun Lara obirin kan ti afi orun wo laso Osupa si mbe labe ese re Ade onirawo mejila lori re O si loyun o nkigbe ni irobi O si wa ninu irora ibimo2Ami miran si han lorun pelu. Dragoni pupa nla kan To ni ori meje ati iwo mewa O fi ade meje si ori re Iru re si wo idameta awon irawo O siju won sori ile ode aye3Satani duro niwaju Maria Nigbati o fe bi Olugbala fun wa Gbana la goe omo na lo sori ite Maria si fo lo si aginju Nibe ni Baba pese aye fun u Kole bo omo na legbefa ojo ole ogota4Mikaeli ati awon omo ogun re Si nba dragoni na jagun Dragoni na ati Angeli re Si dide ogun si Mikaeli Mikaeli si segun dragoni na Apele oruko re ni esu5Nigbana lohun rara kan fo lorun Wipe nigba yi ni igbala de Baba le Olufisun wa jade To nfi wa sun losan ati lorun Gbogbo eda orun si pe ara won Nwon yo ayo isegun lori esu6Ohun kan fo lati ode orun wa O wipe egbeni fun aye Satani lo nyin wa pelu ibinu nla Lati se ohun ibaje lode aiye O mo pe on ko le ba awon angeli ja O pada sodo enia eleran ara.7Gbogbo ori ile ati ede Jeka mura lati ba esu jagun Ki awa le sinu ogbun ile Ki awa ba le wa ninu itura Jeka di amure lati ba esu ja Kale simi bi awon toru ti simi.AminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneAiye e ho ye AlleluyahIFIHAN 12:1-end Previous276 · Eda nla kan lesu waNext 278 · Mo fi iyin fun eleda mimo o loke