No. 296Oju are fo, o foLyrics1Oju ara fo, o fo Egbin wa ninu ifoju aye Oju emi wa sibe O nri iran bi manamana2Okuku le bo oju ojo Sugbon yo di igba asale Sanma le boju osupa Sugbon yo fi imole han3Itiju bo oju ogo aye Sugbon oju ogo emi nriran Eti aye di nipa oro aye Sugbon eti orun ko se4Opa Irin t'owa L'ati ona jinjin yi Nibo lo nlo Baba? Fun mi ni gege re ninu opa yi5Gbogbo okuku nsare lo Nipa ise to ran won Okuku ti o n da nigba orun Ni ese mi yo ba lo6Oju meji fo le de Oju emi meji la Oju emi ti orun O nwo ogo orun7Enu kan lo se Lodo are ese yi Enu mi wa sibe O nsoro ododo Olorun8Ese ara n bo mi mole Bi igbati okuku n bo oju ojo Ni aro kuro ojo Ojo ati osupa yo ran dedeAAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957IMO LORI ESEComposed 30/9/1957 Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous295 · Olorun eleda mi, Iwo ri mi OlofinNext 297 · Ese sa ti le mi ba