No. 297Ese sa ti le mi baLyrics1Ese sa ti le mi ba Ese ti gun ori mi Tani yo lo gba la? L'owo ebi ese mi2Ibiti emi ko fe Lo nsare wo okan mi Ire ti mo nwa kiri On ni emi ko ri3Imo ese bo mi mole Gege bi igbi okun Olorun jo gba mi la L'owo ebi ese mi4Gba mi lowo aisedede mi Gba lowo ebi ese Iwo nikan ni mo se si Baba dariji mi5Imo titun to so jade Ninu okan bi irugbin Bi o se lati odo re wa Je ki nle se tayotayoAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1956IRONU PIWADAComposed on Saturday 5/10/1956Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya9Fi ara re fun Olorun1957 · Orin Isegun Previous296 · Oju are fo, o foNext 298 · Lori oke Rama yi