No. 299Ba wa ba le gba Kristi gboLyrics1Ba wa ba le gba Kristi gbo Ti a n rin ni ipa ase re A o gbe iku mi ni isegun Nikehin ojo aiye wa2E mase ko egbe buburu E mase ko egbe oso Awon omo oso yo parun Olododo yo la3Ninu igbagbo pipe tawa yi E mase wo oro aiye Bi o se taiye la ni ireti Awa je Otosi4Bi a ti le ku ninu Adam Ti n se eni erupe Bi awa ba gbagbo a o jinde Ninu Kristi Oluwa5Bi igbagbo mi ba je pipe Lopin ojo aye mi N o bere pe oro iku da Ajasegun re da6Agbara isa oku da Iku oro re da N o gbe iku mi ni isegun Bi oro Baba paulAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneOlorun odun to koja Previous298 · Lori oke Rama yiNext 300 · Aye lajo mi orun ni ilu mi o