No. 300Aye lajo mi orun ni ilu mi oLyrics1Aiye lajo mi orun ni ilu mi o N o gboro orun ju taiye yi Ko si ere fun mi ninu oro t'aye yi Ere wa fun mi ninu oro ti Olorun2Olorun to se eleda ohun gbogbo N pase fun wa pe ka se ise fun un Gbogbo omo ti ko ba se ise fun Baba Yo jere ina bi orun apadi3Olorun mo de lati se ife re o Esu n gbogun ti mi lojo gbogbo Aye dite mi won fe isubu mi Olorun Elijah jo gbe mi duro4Aye dite si woli Elijah Won si n bere emi re lati gba O pada lo si oke kalmeri Nibe lo fun ni isegun lori ota5Dafidi kepe o lori oke mimo O gbo gbogbo ohun to so si o Mo kepe o, lori oke Eri mo wa Gba mi lowo awon ota mi6Ori oke sinai loro ofin ti wa Oro da ofin O wo inu Mose Ija pari lori oke Mispa Pari ija fun mi lori oke Eri7Orioke giga ti Kristi Oluwa gun Mose ati Elijah fi ara han Nibe ni Jacob ati Johannu ti riran O si fi iran han Peter pelu wonAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryTuneKini Isimi ayo ailopin ni Previous299 · Ba wa ba le gba Kristi gboNext 301 · Ohun oro igbagbo lile