No. 304Siloh ti de ni Ilu eriLyrics1Siloh ti de ni Ilu Eri O duro nibi Påtaki O n kigbe oro Igbala fun wa Kristi joba eje ki a yo Gbogbo Ijo Onigbagbo Jeka yo tori Olofin2Olofin ti fun wa ni ofin Ninu Ijoba ododo Yo ti odo wa fo ijoba aiye Ijoba okukun Ijoba iro Gbogbo Omo Olorun yio gba ofin Ninu Ijoba ti Siloh yi3Nihin ni Ijoba ailekun wa Nihin ni igbala wa Kristi ti fun wa ni Ijoba Lati fo ijoba eke N o layo ni Ijoba Siloh Tori Ijoba alayo ni4Ijoba Siloh fifun wa Ninu re ogbon gbe wa Ninu rẹ ni ihinrere wa Nibe ni itura gbe wa Eni tí o ko ijoba Siloh Yo ku laisi ajindeAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957Composed on the 2nd 12/1957Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous303 · Aye nde Siloh lona o BabaNext 305 · Goligota ibi agbari