No. 303Aye nde Siloh lona o BabaLyrics1Aye n de Siloh lona o Baba (2x) Ona ti Baba fun Siloh won tadi A aye n de Siloh lona o Baba2Ona ti Siloh fe gba aye ko je Eredi re lo fi lo gba ibiti ko ye Ona ti Olofin re fe rin aye ko je3Mori oko kan n rin loju omi O lo gun ibi ikoko ibi ipamo Oko na loko ti Siloh wo4Tani iwo to nrin loju omi Ti o fe simi bi ategun Emi Siloh n ra loju ibu5Gbogbo enyin odo omo obirin Esi ilekun okan yin nu Ki Siloh ba le wo inu okan yin6Tani iwo to n be ni Sioni (2x) To n gba ona erekuru okun de Siloh duro lori awosanma Baba fi oro Siloh si okan mi (2x) Titi Olofin yio fi dé Baba fi omo Siloh fun mi biAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous302 · Lori oke apata KristiNext 304 · Siloh ti de ni Ilu eri