No. 314Oluwa awon to nyo ijo lenu ti po toLyrics1Oluwa awon to nyo ijo lenu ti po to (2x) Opolopo to nsoro si ijo Awon so pe iranlowo kosi fun wa nipa tire Oluwa awon to nyo ijo lenu ti po to2Oluwa yara gbogun ti awon ti n gbogun ti ijo Fi iparun fun awon ti n ba ijo Kristi ja Di apata mi, se Olugbala mi Oluwa yara gbogun ti awon ti n gbogun ti Ijo3Emi fi ohun mi n kigbe pe Oluwa loke Oluwa gbo ohun mi lati oke mimo re wa Nigbati mo sun Oluwa ji mi dide Emi ki yo beru awon ota to yi mika4E se ti awon orile ede fi nbinu fufu? Gbogbo omo oso si n gbero ohun asan Awon oba aye n kese jo Awon ijoye n gbi imo po si Oluwa Ese ti awon orile ede fi nbinu fufu?5Oluwa ti fi oba re je lori oke Sioni Emi o ma rohin ipinu Oluwa lojojo O n wi fun mi pe iwo lomo mi Iwo yo fi opa rin se akoso orile edeAminAbout this hymnWritten byProphet Mennary Previous313 · Emi Jesu gbe omo re o OmoNext 315 · Wo pupo kangan fifo