No. 315Wo pupo kangan fifoLyrics1Wo pupo kangan fifo Ti won ko le gba omi ro Ti n se ogo A! Olorun mi wa se idajo wayi2Awon miran n sotele Beni Olorun ko ran won A! Olorun mi Olorun mi wa se idajo wayi3Awon elo miran n so ede Ti Olorun ko fi ran won A! Iyalenu Olorun mi wa se idajo wayi4Wo bi odi ketekete Ti nfi ohun enia soro A! eru bami Olorun mi wa se idajo aye o5Fere ha le ni kan fon Lai jepe enia fon Kato soro Ka to so ede Olorun yo lo ete wa6Ojo ha le nikan ro L'aije pe ase Oluwa Kato sotele Kato riran Olorun yo fi han ni7Pupo eda lo n sotele Ti won nso iran iku won A! Olorun mi Iwo ko ri won, yara wa be won woAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryEdidi oro Woli eke Previous314 · Oluwa awon to nyo ijo lenu ti po toNext 316 · Ha omo eri rere fun iwo lawa n se ofo