No. 317Gbo bi ara ti n san lokeLyrics1Gbo bi ara ti n san loke Gbogbo elese paramo E fi ara yin fun Kristi Ki e le bo l'owo ese yin2Bi ojo didi ti n ti oke wa Ti ile n fi mu lojojo Beni gbogbo ijoba eke Yo wole logo Siloh3Ijo ti Olugbala pe Ijo awon Aposteli Ati ijo awon Woli Eni ba tele yo la4A o gbe eniyan duro Lori ipilese Woli Ati ipilese Aposteli Kristi je Olori ijo5Woli to ju laiye lorun Ni Kristi omo Olorun Eni ba ko oro Kristi Di anathema maranathaAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957ORIN MIMO NI MONDAY NIGHT 28/1/57Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous316 · Ha omo eri rere fun iwo lawa n se ofoNext 318 · Bi ojo ti nyo ni Ila orun