No. 316Ha omo eri rere fun iwo lawa n se ofoLyrics1Ha omo eri rere Fun iwo lawa n se ofo A n be Baba ko mase gba o Kuro lodo wa. Ha omo ERI rere Tori re lase nsofo2Ko ye ki Akoni wa ku o Ko ye ki ohun ijà wa segbe Ebe mo n be Olorun mi Ko toju eri fun wa Ha omo eri rere Tori re lase n sofo3Egan ba mi tori re Omo Woli oga ogo Baba ran ofa iku pada Kuro larin Ijo re Ha! Omo eri rere Tori re lase n se ofo4Ategun n mi igi olifi O n ro sile o tun n dide Okuku sa bo oju ojo Okuku bo sama Ha! Omo eri oro Fun iwo l'awa n se ofo5Wo bi iji ti n ba oko wa Ti igbi omi si n lu oko na Apa mi ro ese mi ro Gbati mo n reti oro Ha! Omo eri rere Fun iwo lawa n se ofo6Eka to dubule yi Tani o le gbe dide Olorun mi ise re ni Ko si eni to le se Baba jo gbe eri dide Majeki isa oku gbe mi7Ojo iwo sa ma ran Pelu itansan agbara ogo Iri iwo san ma bo Lori gbogbo koriko Baba pase ibukun re Lati oke sori ijo Majeki ari iku aisan Majeki ari aisan ikuAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957ORINMIMO NI MONDAY 28/1/57Won fi orin yi sofo tori omo EriSimilar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous315 · Wo pupo kangan fifoNext 317 · Gbo bi ara ti n san loke