No. 320Apa mi ro ese mi roLyrics1Apa mi ro ese mi ro Kristi boju wo emi omo re Alailera alaimokan lemi otosi elese Orun ododo yara la o Fi oro ododo si ete mi Gbami lowo ebi ese Fi ona imole re han mi.2Ese mi po Oluwa mi Agbara mi ko le gba mi O re mi tan are mu mi Emi ko ri Oluranlowo Orun ododo yara la o Jimi dide ninu orun ese Fi oro Olorun se onje mi Ti emi yio ma je titi lai3Ese mi po bi iyanrin okun Fi agbara Siloh fo ese mi Kristi iwo lo je ki okan mi Kuro lara oku ese Adaba orun yara bo o Gbe omo re le ejika ife Si mi ni isipaya rere Fi agbara emi re won omo re4Aiwe to nsonje Woli re Emi omo re ko le ni nikan Adura opa fitila Ese ko jeki nri aye gba Baba gbe mi si oju ona re Fun mi lemi ta rẹ ki mu Ki n ma ba tun se iyemeji5Emi re to mu bale mi O kere ju fun mi lilo Ko to fun mi lona ERI Ko to fun mi nibi adura Fi emi meje orun wo mi M o mbe o ni Oluwa mi Emi to fun mi koto mi nlo Tu emi re da sori miAminAbout this hymnWritten byProphet MennaryYear1957Similar hymns1Opo eri te ro - Awon omo Eri nsokun1957 · Orin Iyin ati Ọpẹ4Oba Oloro – foro sakoso lori Ijo Tire1957 · Orin Ijo Zion7Afurugbin oro Olorun1964 · Orin Ikilọ8Wo pẹtẹlẹ ologo didan1957 · Orin Isipaya Previous319 · Oro loke oro nileNext 321 · Iwo apata aiyeyaiye Mo fe ki nri o